MORNING PRAYER IN YORUBA!!!

MORNING PRAYER IN YORUBA!!!


MO JI NI OWURO YI 


Good morning Jesus!






Ki agbara Olorun S'amona mi, ki ipa Olorun gbe mi ga 

Ki Olorun to mi si ona, 

ki Olorun si wa ju mi 

Ki Olorun gbo adura mi, 

ki Olorun se Oluso mi 

Ki Olorun fi ona han mi, 

ki Olorun dabobo mi 

Ki Olorun awon omo Ogun orun gbamila kuro 


               Lowo idanwo esu, ati idanwo ese 

               Lowo ohun egbe ti aye, 

               Lowo eni to ni ife buburu si mi 

               Ni ona jinjin ati ni tosi, nigbati mo ba daduro ati 

               Nigbati mo ba wa larin opo eniyan 


Ki Kristi wa pelu mi, ki Kristi wa niwaju ati leyin mi 

Ki Kristi wa ninu mi, Ki Kristi wa lowo otun ati lowo osi mi 

Ki Kristi wa ni bi ibusun mi, ibi iji ati ibujoko mi 

Ki Kristi wa lokan awon ti onronu nipa mi 

Ki Kristi wa lenu awon ti nsoro mi 

Ki Kristy wa loju awon to onwo mi 

Ki Kristi wa leti awon to ngboro mi 

Olugbala ni Oluwa 

Olugbala ni Oluwa 

Olugbala ni Kristi 

Oluwa je ki Igbala re wa pelu wa lailai. Amin!

No comments:

Post a Comment

Show HN: React-decorated-text (first NPM lib, seeking code review) https://ift.tt/f28vYH9

Show HN: React-decorated-text (first NPM lib, seeking code review) https://ift.tt/dGWQLDq May 9, 2024 at 12:47AM